Ajọ to n risi katakara epo rọbi lagbaye OPEC

 1. Epo Bẹntirol

  Agbẹnusọ fun ẹgbẹ IPMAN, Yakubu Suleiman ṣalaye pe, ẹgbẹ naa ti sọ fawọn ọmọ ẹgbẹ lati da iṣẹ silẹ nitori bawọn ọlọpaa ti n dunkoko mọ wọn.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Ẹyin Ọmọ Naijiria, ẹ ma reti lati ra epo bẹntirol ni 200 naira o kere ju - IPMAN

  Arakunrin Osatuyi ni o da oun loju wi pe gbogbo nkan ni yoo gbe owo lori nitori epo bẹntirol lo ma n sọ bi ọja yoo ṣe ri lọrilẹede Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Ẹrọ ita epo bẹntiro

  Ijọba apapọ ti kede pe oun yoo seranwọ fara ilu lati yi ọkọ ati ẹrọ amunawa wọn pada si eyi to n lo afẹfẹ gaasi lọfẹ lati ṣe adinku inira ti ọwọn epo n mu bawọn.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Ile epo

  Minisita keji fun ile iṣẹ epo rọbi, Timipre Sylva ní ipese afẹfẹ gaasi CNG dinwo ju epo bẹntiro lọ lai fi owo kankan kun un lati apo ijọba.

  Kà Síwájú Síi
  next