Ileeṣẹ to nse ọkọ ayọkẹlẹ

 1. Video content

  Video caption: Female Car AC Repairer: Abimbola Adedigba ní àfojúsùn òun ni láti ní abúlé mẹkáníkì láìpẹ́

  Abimbola Adedigba ni iya oun lo se koriya fun oun lati kọ isẹ titun ẹrọ ọlọyẹ inu mọto se, ti oun ko si kabamọ rẹ.

 2. Dino Melaye

  Igbiyanju Sẹneto Dino Melaye lati fi ọkọ Rolls Royce ṣakọ ja si pabo lẹyin ti ile itaja ọkọ kan sọ pe o jẹ awọn ni gbese

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Adebunmi Adeyeye: Mo jẹ gbèsè gbọ́múléláńtà, ìdí iṣẹ́ kabúkabú ni mo ti ri san

  Adebunmi Adeyeye, tii se iya ọlọmọ kan ti ko ni ọkọ, tun sọ ọpọ iriri to ti ni nidi isẹ Kabukabu fun BBC Yoruba.

 4. Ijamba ọkọ bọọsi

  Agbẹnusọ ileeṣẹ panapana ipinlẹ Kwara, Ọgbẹni Hassan hakeem Adekunle lo fidi iṣẹlẹ ọhun mulẹ fawọn akọroyin.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Nigeria Car Innovator: Olatunde Ibitoye ní ọdún mẹ́ta ní òun fi ṣe ọkọ̀ náà torí ọ̀dá owó

  Olatunde Ibitoye ni ọda owo, ohun eelo ati irinsẹ lo n da oun laamu, erongba oun si ni lati se mọto fun lilo ọmọ Naijiria.

 6. Video content

  Video caption: Mayowa Ayodele cab driver: Mi ò lè gbà kí ọmọ mi fẹ ọlọ́pàá láí láí

  Wọn o sanwo, wọn ti i mọle, o tun ti ẹwọn de, wọn fiya jẹ ẹ lori ẹ.