Omi

 1. Video content

  Video caption: Egbejila Fish Village: Àwọn ọlọ́sìn ẹja ní àwọn fi iṣẹ́ báńkì sílẹ̀ wá ṣe ọ̀sìn ẹja ni

  BBC Yoruba de abule ọ̀sin ẹ́ja nipinlẹ́ Kwara ati ọdọ ijọba ipinlẹ naa lati mọ ohun to fa aawọ laarin wọn lori ọsin ẹja to n waye leti odo Asa lagbegbe Egbejila nilu Ilorin.

 2. Video content

  Video caption: Erosion in Ilorin: Kòtò tó wà níbí jìn ju ilé ìgbẹ́ lọ́! Ẹ̀mí wa ò tiẹ̀ balẹ̀ mọ́

  Wọn ṣalaye pe bi awọn ọmọ ba ti wa nileewe bayii, wahala ni.

 3. Video content

  Video caption: World Water Day: Wo ìlú tí èèyan àti àgùntàn, màálù ti ń pín omi kanṣoṣo mu

  Ọpọlọpọ eniyan to fẹ gbe ni ilu naa ni awọn o le maa mu ẹrẹ̀ ni tawọn ni wọn ṣe feré gée.

 4. Video content

  Video caption: Badagry Historical Wells: Omi inú kànga Wawú ló ń kó ọpọlọ àwọn ẹrú lọ

  BBC Yoruba de ilu Badagry lati foju se mẹrin awọn kanga isẹnbaye ti awọn ẹru gbẹ, ki wọn to ko wọn lọ soke okun.