Ajo eleto okoowo lagbaye

 1. Àwọn agbófinró gbàràdá lọ́jọ́bọ lọ́jà Dùgbẹ̀ tó jóná lọ́jọ́rú nílùú Ìbàdàn

  Agbofinro kan n le awọn ọlọkada nibi ọja to jo ni ibadan

  Awọn agbofinro gbarada lọjọbọ nibi lọja Dugbẹ to jona lọjọru nilu Ibadan.

  Nigba ti akọroyin BBC News Yoruba de ọja naa to wa lagbegbe Gbagi atitọ ni ilu Ibadan, gbagbagba lawọn agbofinro atawọn ologun wa nikalẹ lọja naa lati pese abo paapaa julọ lọwọ awọn to lee fẹ lo anfani adanu naa lati tun ja ole nibẹ.

  Dukia ẹgbẹlẹbẹ owo lo jona nibi ijamba ina to waye lọja Dugbẹ nibadan lọjọru.

  Agbofinro kan n le awọn ọlọkada nibi ọja to jo ni ibadan
 2. Mínísítà tó ń rí sí ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèrè ní Nàìjíríà

  Mínísítà tó ń rí sí ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèrè ní Nàìjíríà, Geoffrey Onyeama gba ẹnu ìjọba sọ̀rọ̀ lórí ohun tí yóò ṣokùnfà gan fún títi ìbodè.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Ọkọ̀ àjàgbé

  Mínísítà tẹ́lẹ̀ rí fún ọ̀rọ̀ kátàkárà àti ìdókoòwò, Okechukwu Enelamah ṣàlàyé bí ọmọ Nàìjíríà ṣe lè jẹ àǹfàní rẹ̀.

  Kà Síwájú Síi
  next