Orin

 1. Video content

  Video caption: Sunday Igboho: Timi Orokoya ní orin Iléyá tí òun kọ lọ́dún 28 sẹ́yìn, ló padà wá ṣẹ báyìí

  Timi Orokoya wa rọ awọn asaaju Yoruba lati dide se atilẹyin fun Sunday Igboho nitori bi ohun to n beere fun ba dohun tan, kii se oun nikan ni yoo jẹ anfaani rẹ.

 2. Video content

  Video caption: Wole Soyinka gba BBC Yorùbá lálejò nínú igbó kìjikìji tó kọlé sí

  Báa ṣe ń bi í nípa Soyinka lòun náà ń tọ́ka sí Soyinka kan nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀.

 3. Video content

  Video caption: Glorious Twins: Taiwo àti Kehinde Ekundayo ní ọ̀dọ́ ìyá àgbà ní àwọn ti ẹ̀bún orin kíkọ

  Taiwo ati Kehinde Ekundayo ni awọ̀n orin adura ijọ CAC lo maa n fun awọn ni imisi orin tawọn yoo kọ sita.

 4. Video content

  Video caption: Alhaja Rukayat Batimoluwasi Oniwaka: Orin Wákà la fi ń ṣe Wáàsí, o tó ọdún 70 tí mo tí bẹ̀

  Alhaja Rukayat Batimoluwasi, agba ọjẹ oniwaka ni Ilorin gbalejo BBC Yoruba, o ṣalaye ohun ti oju rẹ ti ri lẹ́nu iṣẹ yii.

 5. Alaseyori, Bamiloye, Tope Alabi

  Ọpọ awọn Ajinhinrere ninu ẹsin Kristẹni lo ti n wo iha ti Tope Alabi yoo kọ si iṣẹlẹ titi to fi wa tọrọ aforiji ni ikini ku oriire ati ajaye ba bẹrẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Video content

  Video caption: Janet Jackson's Yoruba song: Tony Ade ti wọ́n bí sí Amẹ́ríkà ti fẹ́ padà wá Nàìjíríà, ìdí

  Anthony Adewumi ni Janet fẹran bi oun ati ẹgbẹ onilu oun ṣe ko gbogbo ilu Yoruba jọ ti wọn lu u fun un ninu orin rẹ.

 7. Alaseyori ati Tope Alabi

  Nibi ti Yinka Alaseyori ti n ṣe isin orin iyin lati ṣaami ayẹyẹ ọjọ ibi rẹ lo ti bẹ gbogbo awọn eeyan lori ọrọ yii.

  Kà Síwájú Síi
  next