Ẹgbẹ Ẹlẹsin Musulumi

 1. Sultan of Sokoto

  Ajọ NSCIA ṣalaye pe ti wọn ba ri oṣu tuntun lalẹ ọjọ Iṣẹgun, Ọjọru ni Sultan yoo bawọn akọroyin sọrọ tii ṣe ọjọ kinni oṣu Shawwal.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Tunde Bakare ati Bola TInubu

  Tunde Bakare ni ọwọ Ọlọrun ni idajọ wa, ko si yẹ ki awọn eeyan maa fi iwanwara se idajọ ọmọnikeji nitori iwa ti wọn ti hu sẹyin.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Al-Shabab

  Ọdun 1993 ni US ka wọn mọ orilẹede to n sagbatẹru fun ikọ agbẹsunmọmi lẹyin ti Sudan daabobo Osama Bin Laden fun ọdun marun un.

  Kà Síwájú Síi
  next