ifiya jẹni labẹ ile

 1. Yemisi Oyedepo

  Broadcast Journalist

  Captain Walz ti kọ́kọ́ bọ́ra sí hòhò l'àdúgbò kí o tó lọ lu Lẹ́ksọrà ní ọja kejì- Baba Captain Walz

  Iṣẹlẹ yi gbode kan loju opo ayelujara tawọn eeyan si n reti igbesẹ ti fasiti naa yoo gbe lori ọrọ yi

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Aworan

  Wahala bẹrẹ lasiko ti Solution, iyẹn oloogbe, bere lọwọ ọkọ rẹ idi ti yoo fi le awọn akẹkọọ̣ kan kuro nile ẹkọ toun dasilẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. ìyàwó tó ṣán ọkọ rẹ̀ mọ́lẹ̀ tó sí bẹ lórí !

  Iroyin abẹle gbe e pe ede aiyede lo waye laarin awọn tọkọ-taya mejeeji, eleyii to mu ki ọkọ fi ile si ilẹ to si gba oko nkan ọgbin lọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Lola Omolola FIN: A gbọ́dọ̀ dìde láti ran àwọn obìnrin tó ń la ìwà ipá nínú ìdílé lọ́wọ́

  Lola Omolola, tii se oludasilẹ ẹgbẹ awọn obinrin FIN wa rọ awujọ lati dẹkun hihu iwa ipa si ọmọde ati agba obinrin.