Ọja katakara Ipin Idokowo

 1. Video content

  Video caption: Ibadan Gas tanker accident: Ọdọọdún la máa ń gbé igbá àgbo lọ́jà Bode àmọ́ àwọn kan kọ̀ lọ

  Sàráà fún ọjọ́ méje ló yẹ ká ṣe àmọ́ àwọn kan kọ̀ ló fa ìjàmbá Táńkà gáàsì tó pa èèyàn - Iyaloja Bode Ibadan

 2. Ọja Alubosa

  Olori ẹgbẹ awọn Alalubọsa, Isa sọ fún BBC pe ipinu awọn lati ma kó alubosa wo iha Guusu-Ila Oorun ko lee lopin titi di igba ti ijọba ba da alafia kikun pada.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Akure

  Arábìrin Blessing Johnson ati Foluke Ajayi tí wọ́n sọ̀rọ̀ lórúkọ àwọn tó kù sọ pe kí ìjọba tú àwọn adarí náà ká lẹ́yẹ ò sọkà.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Owo naira

  BBC Yoruba ba awọn ipinlẹ kan nilẹ Yoruba sọrọ lori ọda owo tó gbode, gbogbo wọn ni ko si ibẹru.

  Kà Síwájú Síi
  next