Oju ọjọ to buru

 1. Flo Webber stands amongst the debris of her home on the nearly destroyed island of Barbuda which was nearly levelled when Hurricane Irma made landfall with 300km/h winds.

  Ipe wọn yii wa bi ajọ isọkan agbaye se n pinu lati gbe awọn iwadii wọn sita lọjọ aje paapaa julọ nitori bi ayipada oju ọjọ ṣe n peleke si.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Oshogbo Heavy Rainfall: Ọ̀pọ̀ ẹ̀mí àti dúkìá àìmoye mílíọ̀nú naira ṣòfò nínú ìjàmbá omíya

  Ọpọ dukia lo ba iṣẹlẹ naa lọ eyi ti a gbọ pe o bẹrẹ si ni rọ lati oru ọjọ Iṣẹgun ti ko si da titi di owurọ kutu Ọjọru.

 3. Flood: O kéré tán ènìyàn 80 ló ti d'òkú nítori òjò àrọ̀rọdá tó fa omí yalé agbara ya sọọbù

  Ìròyìn sọ pé ní orílẹ̀-èdè Germany, West Germany ni ọ̀rọ̀ náà kàn jùlọ, eyí tí àwọn odò ya wọ ìfgborò tí ọ̀pọ̀ ilé sì rì sí abẹ́ omi.

  Kà Síwájú Síi
  next