Joe Biden

 1. Video content

  Video caption: Joe Biden Innauguration: Tani ìyàwó Joe Biden tí yóò jẹ obìnrin akọ̀kọ nílẹ̀ Amẹrika?

  Ogunjọ, oṣu yii ni wọn yoo burawọle fun Joe Biden gẹgẹ bi aarẹ aadọta ilẹ Amẹrika.

 2. Aworan Biden ati Trump

  Ẹnikẹni to ba fẹ di aarẹ lorilẹ-ede Amẹrika gbọdọ ni ibo to pọ julọ laarin awọn ọmọ igbimọ agbaọjẹ oludibo alaṣẹ (Electoral System)

  Kà Síwájú Síi
  next